nowayobloggers

 • Oloye Obafemi Jeremiah Oyeniyi Awolowo je oluko, akowe iroyin ati amofin.

 • Oje okan lara awon akikanju omo Yoruba to ja fun ominira orile ede Nigeria.

 • Ni odun 1947, ni ipile London, o da egbe omo oduduwa sile.

 • O je oludari akoko ti onisowo ijoba ati ojise ti abele ijoba fun Nigeria.

 • O je eni ti o so Naira ni oruko ti a npe ni ojo oni.

 • O ko liberty stadium ni ilu Ibadan, akoko iru e ni Africa.

 • O tu ko ile cocoa, ti oje ile ti oga ju ni ilu Ibadan.

 • Ni odun 1949, Awolowo fi ipinle iwe iroyin THE NIGERIA TRIBUNE lele, ti oje iwe iroyin ti o dagba ju lo ni ipinle Nigeria.

 • Awolowo je eniyan to fi ipinle eto ilewe eko ofe sile ni western Nigeria.

 •  

  SHARE

  Comments

   NO COMMENT

  Leave Your Comment

  Sign up to continue.

  Your email address will not be published. Required fields are marked.

  Already a member?? Login